Adewale Titus
커뮤니티 튜터
Kíkọ èdè Titun ṣe pàtàkì púpọ, pàápàá jùlọ ede Yorùbá, lotitọ ede nira lati kọ sugbon ibẹrẹ lo nira ni wón igba ti o ba ni afojusun, ka to wí ka to fọ, o tun fi Yoruba dara bi ose wù ọ. Fi orukọ silẹ pẹlu mi ki kọ ọ ni ede Yorùbá. Ose púpọ
2021년 11월 25일 오전 10:55